Warning: Attempt to read property "post_type" on null in /www/wwwroot/islamstore.org/wp-includes/class-wp-query.php on line 4196 Gbígba ènìyàn ní ìyànjú Al-Qur’ān láti máa lo làákàyè rè yóò hàn sí wa níbi ohun tó pò̟, nínú rè̟ ni: – This is Islam Publications
Gbígba ènìyàn ní ìyànjú Al-Qur'ān láti máa lo làákàyè rè yóò hàn sí wa níbi ohun tó pò̟, nínú rè̟ ni:
Al-Qur’ān ń bá ènìyàn, olórí pípé, ẹni tí ọkàn rè sípayá, ẹni tó ní òmìniran kúrò níbi gbogbo ìran ìjegàba, ìgbéraga, ìpayà àti àìmò̟kan, nítorí náà ó máa ń mú è̟rí wá lórí jíjé̟ ò̟ranyàn gbigba Olóhun ní òdodo pèlú àwọn è̟rí tó ní í ṣe pèlú làákàyé àti àwọn è̟rí oríṣiríṣi tó bá ọgbón mu, nínú rè̟ ni: “Àbí a kàn dá won lásán (láìní Elédàá) ni? Àbí àwọn gan-an ni adédàá?- Àbí àwọn ni won dá àwọn sánmà àti ilè? Béè ko, sùgbọn wọn kò mọ àmò̟dájú” (Aṭ-Ṭūr: 35-36).
Parturient ut id tellus vulputatre ac ultrlices a part ouriesnt sapien dignissim partu rient a a inter drum vehicula. Ornare metus laoreet tincidunt eros rolem tristique pretium malada.
Cras rhoncus vivamus luctus platea arcu laoreet selm. Curae est condenectus sed hac a parturient vestibulum.
Reviews
There are no reviews yet.