An e-book in pdf format. Designed for mobile screen size.
* Contains interactive links.
Ṣé kò pàtàkì sí ọ, kí o rí, ní ọ̀nà tí ó fi ojú hàn jùlọ, nípa ẹ̀sìn tí iyàn pọ̀ nípa rẹ̀ jùlọ nínú àwọn ilé àti ìwé ìròyìn tí ó wà ní àyíká rẹ̀?..
Ṣé kò ha tọ́ kí o kóraró fún ìṣẹ́jú kan, nítorí kí o le ní àmọ̀jinlẹ̀, nípa ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀sìn tí ó tàn ká jùlọ ní gbogbo àgbáyé, tí àwọn ènìyàn sì ń wọnú rẹ̀ jùlọ, ní ìbámu sí àwọn kíka òǹkà ìṣẹ̀lẹ̀ àgbáyé?..
Ṣé kò dùn mọ́ ọ kí o wádìí nípa ọ̀làjú àwọn ènìyàn mìíràn àti ìròrí wọn nípa ìṣẹ̀mí-ayé, ẹ̀sìn àti gbogbo àgbáyé tó yí wa ká?..
Kílódè tí o kò ní fún ara rẹ ní àǹfààní láti rí àwọn ẹ̀kọ́ tí a fi ẹ̀rí, láti àwọn ìpìlẹ̀ rẹ̀, gbè lẹ́sẹ̀ nípa ẹ̀sìn Islām … lẹ́yìn náà tí wà á sì gbé ìdájọ́ lé e lórí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ rẹ̀ àti làákàyè rẹ̀?..
Tí o bá rí èyí, tàbí nǹkankan nínú rẹ̀, sí ohun tí ó pàtàkì, tàbí ó jẹ́ ohun tí ò ń jẹ̀rán rẹ̀, a jẹ́ wí pé dájúdájú ìwé yìí yóò jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún ọ láti jẹ́ kí o rí ohun tí ò ń wá..
An e-book in pdf format. Designed for mobile screen size.
* Contains interactive links.
Email: xtemos@gmail.com
Phone: +18 (0) 545 77 32
Email: xtemos@gmail.com
Phone: +18 (0) 545 77 32
Whether you’re looking for answers, would like to solve a problem, or just want to let us know how we did, you’ll find.
Reviews
There are no reviews yet.