Àwòkọ èdè Lárúbáwá

Nígbà mìíràn, ẹnìkan nínú wa, ní ọ̀kan nínú àwọn ọjọ́ ayé, nígbà tó bá lọ bẹ ọ̀kan nínú àwọn ibi ìkóhun-ìṣẹ̀ǹbáyé sí ìlú Òyìnbó wò, níwájú wàláà atọ́ka, èyí tí wọ́n kọ pẹ̀lú àwọn háràfí èdè Lárúbáwá tàbí nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀, ó le rí, láti ipasẹ̀ ohun kan; wàláà atọ́ka, tí wọ́n kọ pẹ̀lú àwọn àwòkọ àti àwọn ohun-ọ̀ṣọ̀ èdè Lárúbáwá, èyí tó fà á lójú mọ́ra, tó sì dá a dúró, kódà kó ṣe fún ìgbà díẹ̀, nítorí kí ó le ronú sí i. Tó bá jẹ́ wí pé nǹkankan nínú èyí kò ṣẹlẹ̀ rí sí ọ, bóyá àwọn àwòràn tó wà lára èpo ìwé yìí, èyí tó wà níwájú rẹ, ti gbẹ ọ́ ní òǹgbẹ láti mọ nǹkankan nínú agbagbe ìmọ̀ yìí. Nítorí náà kín ni ìrò tí àwọn ohun-ọ̀ṣọ̀ àti àwọn iṣẹ́ ọnà, èyí tí àwọn ara ijọ́hun nínú Lárúbáwá àti àwọn mìíràn tó bá wọn lògbà, pegedé níbi dídá àrà pẹ̀lù rẹ̀? Kín ni àṣírí tí ń bẹ níbi rírẹwà rẹ̀? Àti pé kín ni ohun tó ṣe àdáyanrí àwòkọ èdè Lárúbáwá pẹ̀lú ọ̀nà ìmọ̀ yìí, èyí tó fẹ́ẹ̀ má sí nínú àwọn èdè mìíràn?

Register or Login with your Social Account

Register or Login by Email for free download
Please, log in
Description

Double sided A4 color copy paper.

Paper Size: 80-100g

Reviews (0)

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Àwòkọ èdè Lárúbáwá”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

About Islamic civilization

Parturient ut id tellus vulputatre ac ultrlices a part ouriesnt sapien dignissim partu rient a a inter drum vehicula. Ornare metus laoreet tincidunt eros rolem tristique pretium malada.

Cras rhoncus vivamus luctus platea arcu laoreet selm. Curae est condenectus sed hac a parturient vestibulum.

technical description

OUR ADDRESS

New York

56 E. Fieldstone Street
Summerville, SC 29483

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

Paris

28 Boulevard des
Capucines, 75009

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

CONTACT US

Whether you’re looking for answers, would like to solve a problem, or just want to let us know how we did, you’ll find.

Register

Your personal data will be used to support your experience throughout this website, to manage access to your account, and for other purposes described in our privacy policy.