Báwo ni yóò ti rí Ebùn ìbuyìfúnni (Nobel) Odún 1130 C.E

Olajù è̟sin Islām joba lórí gbogbo àgbáyé fún ohun tó lé ní 800 odún, láàrin ìgbà tó bèrè láti (630 – 1430) léyìn bíbí Ànábi ‘Tsā. Agbáyé èsin Islām, ní ìgbà náà, pèlú èdè rè tó jé Lárúbáwá, òun ni onkà ákó̟kó̟ fún ìmò̟ àti ìmòye. Dájúdújú ìmò̟ dé ògóngò rè, ní àsìkò ti won n pè ní àwọn ìgbà è̟sin Islām tó yanran-ntí. Nítorí pé ògò̟ò̟rò àwọn onímímo jáde síta, tí wón jé ògúnná gbongbò nibi àwọn agbagbe ìmò̟ işé-işègùn, imò nípa ojú-ojó, işirò àti ìmò̟-è̟ro. Ní ìgbà náà, opolopo àwọn akékoó, láti olókan- ó-jokan àwọn ààyè lórí ile máa ń wá sí ò̟dò̟ won láti wá kó è̟kó̟ lódo won. Awọn ìwé wọn àti àwọn işé-iwadií wọn sí je ohun ti won n ko ní àwọn kan nínú àwọn Yunifásíti ní àgbáyé, gégé bí nnkan ti rí pelú àwọn ìwé tí àwọn onímìmò̟ méjèèji yìí; Ibn Sīnā àti Al-Khawarizmi ko, àti àwọn àgbà-oje onímimo miíràn, tí wón ń ko àwọn ìwé won ni Yunifásíti àtijó Sorbornne, èyí tó wá ní ìlú Faransé títí di ìgbà tí ọrúndún yìí lé ní ogún ọdún.

Register or Login with your Social Account

Register or Login by Email for free download
Please, log in
Description

Panels: in longitudinal and transverse dimensions of A2 dimensions.

Longitudinal banners: Size: 80cm * 200cm

Reviews (0)

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Báwo ni yóò ti rí Ebùn ìbuyìfúnni (Nobel) Odún 1130 C.E”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

About Islamic civilization

Parturient ut id tellus vulputatre ac ultrlices a part ouriesnt sapien dignissim partu rient a a inter drum vehicula. Ornare metus laoreet tincidunt eros rolem tristique pretium malada.

Cras rhoncus vivamus luctus platea arcu laoreet selm. Curae est condenectus sed hac a parturient vestibulum.

technical description

OUR ADDRESS

New York

56 E. Fieldstone Street
Summerville, SC 29483

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

Paris

28 Boulevard des
Capucines, 75009

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

CONTACT US

Whether you’re looking for answers, would like to solve a problem, or just want to let us know how we did, you’ll find.

Register

Your personal data will be used to support your experience throughout this website, to manage access to your account, and for other purposes described in our privacy policy.