Báwo ni yóò ti rí Ẹ̀bùn ìbuyìfúnni (Nobel) Ọdún 1130 C.E

Ọ̀làjù ẹ̀sìn Islām jọba lórí gbogbo àgbáyé fún ohun tó lé ní 800 ọdún, láàrin ìgbà tó bẹ̀rẹ̀ láti (630 – 1430) lẹ́yìn bíbí Ànábì ‘Īsā. Àgbáyé ẹ̀sìn Islām, ní ìgbà náà, pẹ̀lú èdè rẹ̀ tó jẹ́ Lárúbáwá, òun ni òǹkà àkọ́kọ́ fún ìmọ̀ àti ìmòye. Dájúdújú ìmọ̀ dé ògóńgò rẹ̀, ní àsìkò tí wọ́n ń pè ní àwọn ìgbà ẹ̀sìn Islām tó yanran-ntí. Nítorí pé ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn onímímọ̀ jáde síta, tí wọ́n jẹ́ ògúnná gbòǹgbò níbi àwọn agbagbe ìmọ̀ iṣẹ́-ìṣègùn, ìmọ̀ nípa ojú-ọjọ́, ìṣirò àti ìmọ̀-ẹ̀rọ. Ní ìgbà náà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àkẹ́kọ̀ọ́, láti ọlọ́kan-ó-jọ̀kan àwọn ààyè lórí ilẹ̀ máa ń wá sí ọ̀dọ̀ wọn láti wá kọ́ ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀ wọn. Àwọn ìwé wọn àti àwọn iṣẹ́-ìwadìí wọn sí jẹ́ ohun tí wọ́n ń kọ́ ní àwọn kan nínú àwọn Yunifásítì ní àgbáyé, gẹ́gẹ́ bí nǹkan ti rí pẹ̀lú àwọn ìwé tí àwọn onímìmọ̀ méjèèjì yìí; Ibn Sīnā àti Al-Khawārizmī kọ, àti àwọn àgbà-ọ̀jẹ̀ onímìmọ̀ mìíràn, tí wọ́n ń kọ́ àwọn ìwé wọn ní Yunifásítì àtijọ́ Sorbornne, èyí tó wá ní ìlú Faransé títí di ìgbà tí ọrúndún yìí lé ní ogún ọdún.

Register or Login with your Social Account

Register or Login by Email for free download
Please, log in
Description

Double sided A4 color copy paper.

Paper Size: 80-100g

Reviews (0)

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Báwo ni yóò ti rí Ẹ̀bùn ìbuyìfúnni (Nobel) Ọdún 1130 C.E”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

About Islamic civilization

Parturient ut id tellus vulputatre ac ultrlices a part ouriesnt sapien dignissim partu rient a a inter drum vehicula. Ornare metus laoreet tincidunt eros rolem tristique pretium malada.

Cras rhoncus vivamus luctus platea arcu laoreet selm. Curae est condenectus sed hac a parturient vestibulum.

technical description

OUR ADDRESS

New York

56 E. Fieldstone Street
Summerville, SC 29483

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

Paris

28 Boulevard des
Capucines, 75009

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

CONTACT US

Whether you’re looking for answers, would like to solve a problem, or just want to let us know how we did, you’ll find.

Register

Your personal data will be used to support your experience throughout this website, to manage access to your account, and for other purposes described in our privacy policy.