Ẹ̀sìn Islām àti títan òmìnira ká

Nígbà tí ẹ̀sìn Islām dé, ẹrú jẹ́ nǹkan yẹpẹrẹ, kò pàtàkì, kò sì ní ẹ̀tọ́ kankan, dájúdájú ó jẹ́ ẹni tí kò ní àpọ́nlé kankan rárá. Bíbá a lò kò sì ní àjọṣepọ̀ kankan pẹ̀lú jíjẹ́ ènìyàn, kò jẹ́ nǹkankan bíkòṣe ẹni tí ǹ bẹ fún ṣíṣiṣẹ́ sin ẹlòmíràn àti ohun èlò lásán. Kódà kò sí ohun tó burú níbi kí wọ́n kó ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ sí i lẹ́sẹ̀, nígbà tó ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́, nítorí kí ó má baà sálọ. Kò sí ohun tó burú níbi kó kú tàbí kí wọ́n pa á, tó bá ti jẹ́ wí pé yóò fa ìtẹ́lọ́rùn àti ìgbádùn gẹ́gẹ́ bí ó ti wà níbi àwọn ìjàkadì ilẹ̀ Rūm tó gbajúmọ̀ ní Colosseo, èyí tí àwọn ẹrú máa ń bá ara wọn ja ìjàkadì níbẹ̀ títí dé ojú ikú láti tátán ti ìtànjẹ àti ìgbádùn àwọn ọ̀gá wọn.

Register or Login with your Social Account

Register or Login by Email for free download
Please, log in
Description

Double sided A4 color copy paper.

Paper Size: 80-100g

Reviews (0)

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Ẹ̀sìn Islām àti títan òmìnira ká”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

About Great Islamic values

Parturient ut id tellus vulputatre ac ultrlices a part ouriesnt sapien dignissim partu rient a a inter drum vehicula. Ornare metus laoreet tincidunt eros rolem tristique pretium malada.

Cras rhoncus vivamus luctus platea arcu laoreet selm. Curae est condenectus sed hac a parturient vestibulum.

technical description

OUR ADDRESS

New York

56 E. Fieldstone Street
Summerville, SC 29483

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

Paris

28 Boulevard des
Capucines, 75009

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

CONTACT US

Whether you’re looking for answers, would like to solve a problem, or just want to let us know how we did, you’ll find.

Register

Your personal data will be used to support your experience throughout this website, to manage access to your account, and for other purposes described in our privacy policy.