Ìtàn ọ̀tun ń bẹ, nínú Al-Qur’ān, nípa Ànábì ‘Īsā – kí ọlà Ọlọ́hun máa bá a –

Ànábì ‘Īsā – kí ọlà Ọlọ́hun máa bá a – jẹ́ ara àwọn ènìyàn tí ó pàtàkì jùlọ láti ìgbà-dégbà, ó sì wà lára àwọn tí ó tóbi jùlọ nínú àwọn ẹni tí ó mu dáadáa wá fún ìran ọmọnìyàn. Àwọn ènìyàn yapa ara wọn níbi ìgbàgbọ́ wọn nípa rẹ̀; láàrin ẹni tí ó kà á sí ọlọ́hun tàbí ọmọ Ọlọ́hun Ọba, àti láàrin ẹni tí ó mú un ní ọ̀tà, tí ó ń fi ẹnu ẹ̀tẹ́ àti àwọn ẹ̀sùn ìbàjẹ́ kàn án. Nítorí náà, kí wá ni ipò Al-Qur’ān nípa Ànábì ‘Īsā – kí ọlà Ọlọ́hun máa bá a –?

Register or Login with your Social Account

Register or Login by Email for free download
Please, log in
Description

Double sided A4 color copy paper.

Paper Size: 80-100g

Reviews (0)

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Ìtàn ọ̀tun ń bẹ, nínú Al-Qur’ān, nípa Ànábì ‘Īsā – kí ọlà Ọlọ́hun máa bá a –”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

technical description

OUR ADDRESS

New York

56 E. Fieldstone Street
Summerville, SC 29483

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

Paris

28 Boulevard des
Capucines, 75009

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

CONTACT US

Whether you’re looking for answers, would like to solve a problem, or just want to let us know how we did, you’ll find.

Register

Your personal data will be used to support your experience throughout this website, to manage access to your account, and for other purposes described in our privacy policy.