Kín ni ohun tó fà á, tí wọ́n fi fẹ́ mọ̀ nípa ẹ̀sìn Islām?

Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, ènìyàn máa ń lo agbára láti sọ ìròrí rẹ̀ dí ọ̀ranyàn lórí ẹlòmíràn, àti lápa lára wọn àti láti jẹ́ kí ohun tí yóò ṣe é ní àǹfààní tẹ̀ ẹ́ lọ́wọ́. Ìtàn ayé yìí kún fún àwọn àpèjúwe lórí èyí fún gbogbo àwọn ìjọ, nínú àwọn tó ń fi ara wọn tí sí àwọn ẹ̀sìn àti àwọn ìlànà oríṣiríṣi.
Ìtàn ayé yìí, ní àpèjúwe, jẹ́rìí sí i pé dájúdájú àwọn ìgbìyànjú ṣíṣe àfọ̀mọ́ àwùjọ tí wọ́n ṣe ní ọ̀ṣọ́, wáyé fún àwọn tó jẹ́ ògodì ọmọ-ìlú, nígbà tí àwọn olùwadìí, àti àwọn tó fi ìlú wọn sílẹ̀ dé ibi àgbáyé titun, débi wí pé àlùfáà Kìrìsìtẹ́ní, tó jẹ́ ara orílẹ̀-èdè Spain, Bartolome de las, ṣàlàyé èyí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ rẹ̀, nígbà tó rí àwọn ààyè tí wọ́n ti ṣe ẹ̀mí àwọn ènìyàn lófò, pé: “Dájúdájú wọn kò fi ojú tí wọ́n fi ń wo ènìyàn wo àwọn tó jẹ́ ògodì ọmọ-ìlú, ṣùgbọ́n wọ́n kà wọ́n sí ẹni tó yẹpẹrẹ, kódà ju àwọn ẹranko lọ”.
A Brief Account of the Destruction of the Indies by Bartolome de las Casas (Jan 1، 2009)

Register or Login with your Social Account

Register or Login by Email for free download
Please, log in
Description

Double sided A4 color copy paper.

Paper Size: 80-100g

Reviews (0)

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Kín ni ohun tó fà á, tí wọ́n fi fẹ́ mọ̀ nípa ẹ̀sìn Islām?”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

About Great Islamic values

Parturient ut id tellus vulputatre ac ultrlices a part ouriesnt sapien dignissim partu rient a a inter drum vehicula. Ornare metus laoreet tincidunt eros rolem tristique pretium malada.

Cras rhoncus vivamus luctus platea arcu laoreet selm. Curae est condenectus sed hac a parturient vestibulum.

technical description

OUR ADDRESS

New York

56 E. Fieldstone Street
Summerville, SC 29483

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

Paris

28 Boulevard des
Capucines, 75009

Email:  [email protected]
Phone:  +18 (0) 545 77 32

CONTACT US

Whether you’re looking for answers, would like to solve a problem, or just want to let us know how we did, you’ll find.

Register

Your personal data will be used to support your experience throughout this website, to manage access to your account, and for other purposes described in our privacy policy.